how the mighty falls..............

Date: 27-04-2011 11:08 pm (12 years ago) | Author: AFOLABI ADEKUNLE KABIR
- at 27-04-2011 11:08 PM (12 years ago)
(m)
 ah!!! olorun oba ooooooooooooooo..... oba elesan ma ni yin o.... ase ko si agbara ti a le fi we ti yin..... a se, igbati yoruba bo ti won ni, ogun lo lojo iponju, ori eni lo lojo gbogbo, a se o ni ohun ti won ri.... e wa wo igbeyin christopher ni ilu Ibadan.... a se gbogbo kurakuta ma dopin... kinni igbeyin ebo won... omo tuntun jojolo ti won ko ifun e jade ti won fi rubo.... eje alaboyun... eje aika moye eda nile guru. nibo gbogbo eleyi gbe won de? kinni orin aro ti a le ko fun ru eni bayi... o le jo bi epe, sugbon e ma ri bi epe e, aso to ba ye la da fun ijo... emi o bere ohun meji lowo eyin eniyan, e sa ma se ase, ase ase..
won ni ti lanka, ti lanka, ti lanka ti lanka, won e ri omo lehin ejo, alao adebayo, o ni r'omo gbeyin aye e. atilo atibo, ni teran oje, enit'o gbodo mi kan o n ni isimi, wahala, idamu o n je a gbe fere oba fon, wahala, idamu, airoju, airaye, siba sibo, ti da gbre fun wa nilu Ibadan ati gbogbo ipinle oyo poron godo, won gbe 'ru won o di ile adebayo alao christopher... won o pile se ago fun onile, toripe won mo pe alaga awon ni landlord. awon onile gan o se meni, se meji, won gba eru lori awon alejo oran, won pale yara fun won, won de fo gere bale.Akinkunmi Adekunle Ayinla too ibo ni gomina ana fe lo bayi, tori, awon Yoruba bo won ni, ile o gba ona o gba, ni se ewe aaragba. inu igbo l'obo n gbe. won e ko'le adete si igboro. adebayo alao, odo o ki nsan ko boju wehin igbo rere, rere, ko lo ma ba ebora jeun. ofo bayi ni t'omi efo, gbogbo ohuno f'eru kojo lati ibere pepe aye a fi e sile saye lo ni lagbara Eledua. ofo yi o ni je tie nikan o,tomo, tomo, tebi tara, lati ori iran kinni, titi to de keje, ni ofo yi ma ba. eyi a wi, aro a ro mo. moti moti n'iwo agbo moti, taka se nise lawujo owu, tooooooooooooooooo, ase......
                                                     

Posted: at 27-04-2011 11:08 PM (12 years ago) | Newbie
- soljurn16 at 28-04-2011 12:02 AM (12 years ago)
(m)
Igbeyin lo'oju., esan a kee o.., igbeyin asekaa kii'nda o
Posted: at 28-04-2011 12:02 AM (12 years ago) | Upcoming
Reply