Lagbaja : Akebaje

Date: 26-01-2008 6:57 pm (16 years ago) | Author: King Samuel O Dguy
- at 26-01-2008 06:57 PM (16 years ago)
(m)
Mo ti dagba / Mo ti balaga / O to ki ngbeyawo / Mo ba ni / Ki nmu baby dele / Ololufe mi / Aje butter pata / Akebaje, omo ti rindin pata o / Akebaje, oti rindin pata o

Ko ma le gunyan / Mo ra pounder / Ko ma le lota / Mo ra blender / Ko ma le sebe / Mo gba cook /Akebaje o le gba'le / Mo ra vacuum / Ko ma le foso / Mo gba drycleaner / Ko ma le toju omo o / Mo gba nanny

Ko ma kuku se pe / Ko le sebe rara / Amo kaka ki njejekuje / Ma ya pebi mora / Akebaje se'be eran / Aja gan o le fije / E ye nje ko ti fail pata o / O fail, O gbodo / Akebaje, o fail pata / Nje e ma woye pe / Akebaje useless / Se lo ye ki nfi sile / Ko maa lo / Oti o / Nkankan wa t'akebaje moo se o / Iyen si te mi lorun patapata / Eee, O te mi lorun / Ee, Akebaje / (Scat) Ayan oya lulu f'akebaje kaa ri ijo butter

Chant: Ko i ye won / Yio ye won lola

Eni to se idanwo / To gba one upon ten / E dakun nje ko ti fail pata / Amo one lokn yen / Ti akebaje gba / Iyen lo se pataki patapata / Ee, nkankan soso se lakebaje moo se o / Iyen si te mi lorun patapata / Ee akebaje / Emi o mama lee fi o le / One upon ten, o te mi lorun, akebaje


Posted: at 26-01-2008 06:57 PM (16 years ago) | Gistmaniac