Mo ro pe iyen ku si owo iyawo fun ra ra e . Nitori awon yooba bo . won ni. "Bo se wu ni la nse a se imale eni"
Mo lero pe laye ode oni . Ti ife ba wa larin ololufe meji ife yen maa nfi oju fo alebu . nitori kini ? Nitori pe . Afoju nife .
Ba kan naa ewe . obirin ti o ba fi ara re wole laarin okunrin pupo le ni isoro lati ri omokunrin ti yio dide fun un lati fi se aya .
Awon yooba bo won ni aku kuubi san se rada rada . honeypot o se bi owe
Ese, o to leso nipa danger to wa ninu pe ki obirin fi ara e wole (tin ba si yin gbo, to tunmo sipe ki obirin ma se bi aja) hmmm ...... o se mi lanu pe most obirin nisinyi won de ka si. Won ma ro pe awon jaye ni. O de da ki omoobirin in Iya gigi to ma ko leko lati kekere.
Posted: at | |