wunzie at 20-07-2010 09:10 PM (13 years ago) (f) Mi mo o buroda wa, emi kan ti Vixenx leyin ni. Abi ti enyan ba so pe bebe nlo, seebi idan lo leyan maso tele?
FAKE PROFILES DOESN'T BOTHER ME ONE BIT, UNLESS PEOPLE HIDE BEHIND THEM TO SPIT VENOM. SHOW THE BOLDNESS OF A LION NEXT TIME......USE YOUR ORIGINAL PROFILE!! Posted: at 20-07-2010 09:10 PM (13 years ago) | Gistmaniac | |
Reply |
Awon agba bo, won ni "Eshin iwaju ni ti eyin n wo sare" kilo wa de ti awon omo kotu ojire ko lati dasi eto yi? Oun ani langbe laruge ke. Ema je ko lo sile rara. E se pupo Posted: at 21-07-2010 06:22 PM (13 years ago) | Upcoming | |
Reply |
spekay at 21-07-2010 08:54 PM (13 years ago) (m) Mi mo o buroda wa, emi kan ti Vixenx leyin ni. Abi ti enyan ba so pe bebe nlo, seebi idan lo leyan maso tele?
mo ngbo tiyin eniyan iyi won ni ko sewu loko .... afi giiri aparo
" If its not for love - its for nothing " [/size] Posted: at 21-07-2010 08:54 PM (13 years ago) | Gistmaniac | |
Reply |
spekay at 21-07-2010 09:00 PM (13 years ago) (m) Awon agba bo, won ni "Eshin iwaju ni ti eyin n wo sare" kilo wa de ti awon omo kotu ojire ko lati dasi eto yi? Oun ani langbe laruge ke. Ema je ko lo sile rara. E se pupo
buroda wa e si ku amoran to loye. mo si gba tiyin doba sebi ohun a ni la ngbe laruge..... e ku idide o e si ku amulero ko ni baje... fun wa
" If its not for love - its for nothing " [/size] Posted: at 21-07-2010 09:00 PM (13 years ago) | Gistmaniac | |
Reply |
eyin temi, eku ikale, se ewa pa, se gbogbo eh nlo deedee Posted: at 23-07-2010 11:42 AM (13 years ago) | Upcoming | |
Reply |
spekay at 23-07-2010 11:53 AM (13 years ago) (m) eyin temi, eku ikale, se ewa pa, se gbogbo eh nlo deedee
E ku abo o anti Dupsy . A si ku faaji opin ose. Ile nko. Ki emi ola o gun o ..
" If its not for love - its for nothing " [/size] Posted: at 23-07-2010 11:53 AM (13 years ago) | Gistmaniac | |
Reply |
amin oo, faaji opin ose yi ma serious gan ni, adupe lowo Olorun ti o da emi wa si di ojo oni. Posted: at 23-07-2010 12:18 PM (13 years ago) | Upcoming | |
Reply |
spekay at 23-07-2010 12:26 PM (13 years ago) (m) Abi o . mai sista ope fun ohun gbogbo . mo ngadun tope Alabi lori website yin ma . Se e wa . !
" If its not for love - its for nothing " [/size] Posted: at 23-07-2010 12:26 PM (13 years ago) | Gistmaniac | |
Reply |
acaalliy at 23-07-2010 12:37 PM (13 years ago) (m) Opolopo yin ko tile le ko yoruba yanranti, o maa se o, o kare laye Spekay omo yoruba to yanranti, Akosile re dara o dun kaa. baa ba ka eru inu eru a baje... Eyin omo Odua mo ki gbogbo yin o... Posted: at 23-07-2010 12:37 PM (13 years ago) | Upcoming | |
Reply |
"laffing out loudly " eleyi kamama , lol @acailly..... iwo ma try gaannn nio, omo yoruba gidi nie, akosile tie gan na dun bi oyin igan. igbati emi lo si sukulu, mio ra we akomolede yoruba, nitorina ni yoruba mi o se yanranti . se e ti gbo sir ? @spekay.... ese gan ni sir , ti e ba wa fi ikale gbo orin tope alabi na, ese oo. awa le wa dupe oo Posted: at 23-07-2010 12:52 PM (13 years ago) | Upcoming | |
Reply |
spekay at 23-07-2010 12:53 PM (13 years ago) (m) Opolopo yin ko tile le ko yoruba yanranti, o maa se o, o kare laye Spekay omo yoruba to yanranti, Akosile re dara o dun kaa.
baa ba ka eru inu eru a baje... Eyin omo Odua mo ki gbogbo yin o...
E maa wole oo buroda mi e ku ayesi wa Ko ni ba je fun wa . Ki emi ola o gun
" If its not for love - its for nothing " [/size] Posted: at 23-07-2010 12:53 PM (13 years ago) | Gistmaniac | |
Reply |
Ti awon omo yanmiri ati awon omo aboki ngbona felifeli bi amala to jina dandan, sugbon o se ni laanu wipe ti awa omo kotu ojire n tutu nini lori naija pal. kilo nsele, e ba wa da si eto yi. Eku faaji opin ose, Lagbara Oluwa, a san wa sowo, omo ati aiku baale oro. Posted: at 23-07-2010 12:56 PM (13 years ago) | Upcoming | |
Reply |
spekay at 23-07-2010 01:01 PM (13 years ago) (m) "laffing out loudly " eleyi kamama , lol
@acailly..... iwo ma try gaannn nio, omo yoruba gidi nie, akosile tie gan na dun bi oyin igan. igbati emi lo si sukulu, mio ra we akomolede yoruba, nitorina ni yoruba mi o se yanranti . se e ti gbo sir ?
@spekay.... ese gan ni sir , ti e ba wa fi ikale gbo orin tope alabi na, ese oo. awa le wa dupe oo
LOL o kama ma gan an ni Yoruba dun ka . inu mi si dun lati ba yin pade. . anti Dupsy yooba yin ka ma ma o yaranti Mi o je fi yin jafara oo . . Eni ti abi to tun tun ra e bi. Orin Tope Alabi dun gbo seti oo . afi bi Irawo owuro .
" If its not for love - its for nothing " [/size] Posted: at 23-07-2010 01:01 PM (13 years ago) | Gistmaniac | |
Reply |
spekay at 23-07-2010 01:09 PM (13 years ago) (m) Ti awon omo yanmiri ati awon omo aboki ngbona felifeli bi amala to jina dandan, sugbon o se ni laanu wipe ti awa omo kotu ojire n tutu nini lori naija pal. kilo nsele, e ba wa da si eto yi. Eku faaji opin ose, Lagbara Oluwa, a san wa sowo, omo ati aiku baale oro.
ooto loro yin oo ebi mi . awon omo yanmirin papa ngba ile yi koja lati gbadun eto wa koda awon alawo funfun gbadun eto yooba . mo si lero pe awon eniyan wa nbo lati ba wa gbe eto yi la ruge lai pe jojo
" If its not for love - its for nothing " [/size] Posted: at 23-07-2010 01:09 PM (13 years ago) | Gistmaniac | |
Reply |
aile ko yoruba ni o nse won , ti won ko fi le dasi oro na Posted: at 23-07-2010 02:33 PM (13 years ago) | Upcoming | |
Reply |
aile ko yoruba ni o nse won , ti won ko fi le dasi oro na
Hmmmn..... OMG, Opo omo yoruba ti di eru edekede, ki olorun ran won lowo! Mi mo o buroda wa, emi kan ti Vixenx leyin ni. Abi ti enyan ba so pe bebe nlo, seebi idan lo leyan maso tele?
mo ngbo tiyin eniyan iyi won ni ko sewu loko .... afi giiri aparo Ose Pupo, Olorun awa pelu re ati gbogbo awon ti won ko lati ta ede ati asa won lowo pooku. Posted: at 23-07-2010 03:12 PM (13 years ago) | Upcoming | |
Reply |
acaalliy at 23-07-2010 03:22 PM (13 years ago) (m) "laffing out loudly " eleyi kamama , lol
@acailly..... iwo ma try gaannn nio, omo yoruba gidi nie, akosile tie gan na dun bi oyin igan. igbati emi lo si sukulu, mio ra we akomolede yoruba, nitorina ni yoruba mi o se yanranti . se e ti gbo sir ?
@spekay.... ese gan ni sir , ti e ba wa fi ikale gbo orin tope alabi na, ese oo. awa le wa dupe oo
Dupsyexotic. Yoruba Akomolede to kaa lemi na kaa, beeni Omo yoruba ogidi lonsoro lati ilu Ibadan. Mosi kiekie o se gaan ni o. Mo ri e ki nto kie, mosi kie ki nto ri e... Posted: at 23-07-2010 03:22 PM (13 years ago) | Upcoming | |
Reply |
delemang at 23-07-2010 08:17 PM (13 years ago) (m) Eyin tiwa n tiwa Posted: at 23-07-2010 08:17 PM (13 years ago) | Upcoming | |
Reply |
princedafe at 23-07-2010 11:01 PM (13 years ago) (m) WHAT A SENSELESS POST NP IS NOT ONLY FOR YORUBAS!!!!!!!!!!!!!!!! Posted: at 23-07-2010 11:01 PM (13 years ago) | Gistmaniac | |
Reply |
spekay at 24-07-2010 12:53 AM (13 years ago) (m) WHAT A SENSELESS POST
NP IS NOT ONLY FOR YORUBAS!!!!!!!!!!!!!!!!
Some dey follow follow dem close dem eyes . dem close eyes pin pin pin Na which side you follow come sef ? IGI WOROKU TI NDA INA RU . "Komi alo, ko mi alo . komi alo oo ooooo Awa o foloshi legbe wa . "' .
" If its not for love - its for nothing " [/size] Posted: at 24-07-2010 12:53 AM (13 years ago) | Gistmaniac | |
Reply |